Sunteți pe pagina 1din 3

OGUN ALEKO TO DAJU Orogbo, obi gbanja, etu ibon, ako okuta,

esuru funfun, ege ti a nfi ngun iyan je, ogede agbagba dudu, agbado,
iyere ao fi sugar die si ao gun po ao maa fi foko tutu mu.
OOGUN ATIKE TI OKUNRIN FI N FERAN OBINRIN
Obinrin na yio mu orogbo kan si abe re moju, a o gba ni ojo keji, a o
gun orogbo na pelu epo bodunbawo ti o wo sile funrare ati ifo ejo die,
a o lo kunna dada, a o po mo atike, obirin na yio ma ku si oju re.
OSE AWURE YI DARA.
Ao ja ewe kan lori igi ibepe ti o so dada, ao bu die ninu iyepe oja ti o
kun dada, erupe orita meta, ati erupe akitan ti o gba ore, ao gun po
ao fi oyin gidi po, pelu ose ao fi omo ayo kan gun lori, ao ko sinu ike
funfun ao ma fi we o daju.
AKOYA ABENU GONGO TOGBONA: ewe ailu, ewe
kilofefimise, ewe mafowokan omo mi, ewe
atikaparare, ewe gbegbe, ewe tete, awo ekun die,
epo obo, odidin atare kan, ao lo wa ikaraun ibin to tobi
ninu igbo, (ibi ti won ba ge imo ewe ope eyin si, ni eti
le saba ri ikaraun ibin, tabi ki e so fun awon elewe o mo ki won ba yin
wa, amo ko je ti korofo ikaraun ibin
tinu igbo gan gan, ao ko gbogbo awon eroja yi sii
ikaraun ibin na. Ao fi aso pupa bo ooo loju, a o fi owu
dudu ati funfun di ni iko bere ti ara re ko ni han sita,
(owu iranso lao lo) ao lo ri mole si orita meta ni oru
(night) fun ojo meta, to ba ti di ojo keta, ao lo wu kuro nibe ni ale, ao
jo lai tu, ao lo kunnaa, ao da si meta, afi
idan kan: sin gbere yii abadi wa ka, ao wa sin bere
ejiogbe si (center) lona meta si isale re.
||
||
|| Ao fi idakeji: ao ko lose dudu, ao ko sinu iba funfun,
after 7days, lao fi we ni ago kan osan lekan soso.
AO FI IDA KETA: ao da sinu awo funfun ao we ni tira
pelu owu dudu ati pupa, ao fi aso pupa ran ni olounde
ao wa fi owu ibile dudu ati funfun we round ti olounde
yen ko ni han jade, ao ma wo si ibadi, after 7days ti aba ti fi ose yen
we ni ao ma wo siidi.
AKIYESI: ao ni je ki omi kan oju gbere yen fun ajo meje
gbako, amo ele ma shin apa shin ese. Ao si ni ma fi
olounde yen we, ao ma bo (remove) ti aba fe we.
ISE OGUN YII: apota: se eyin gbo pe omi ti eyin wo igbin

lenu re ni ? ti won ba sa ogun siwa lati fi pe ori wa ni bi, oso ni, aje ni,
elebologun ni, tabi emere, walahi
eninaa yio pa arare ni ooo.
Maran: ogun yii deenaa kiko aisan ni pa ibasun tabi ti
won ba le magun fun obinrin, ti aba ba ni ajosepo, tabi
ti won ba fi ogun gbawa, ko si nkan ti yo se wa
aforan: ojo ti ijanba ba fe sele si wa, o le je ija n ba MOTO, tabi OLE, or
OGUN (war) ti nkan ba sele si gbo
gbo won, ko si ikan ti yio o sele si wa, lai fi arapa. Etc
Asegbe: ibi ti won ba niki gbegbe ma gbe ibe ni gbe,
ibi ti won ba ni ki tete ma te ibe ni n te, ti aba wuwa
ibaje ko si eni ti yio bi wa ooo
OOGUN ALEKO
ori eJo sebe kan, ori alabahun kan. odidi Atare kan, ao Jo papo, ao wa
lo ebu ogun po mo etu ibon gidi, ao ma fi fo eko tutu mun.
Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se
inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele
fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori email...sugbon kii se ofe o.
Biiii eloooo niii.

EBE AWON AGBA TI A N PE NI FAYEGBAMI.


asin 1
oga gbigbe 1,
odindi atare 1,
isu ogirisako ao gesi kekeke lona 7,
ao jo po ao lo kunna, ao ma pe ofo re si; Aje ile won kii dari jo je oga
oko, aje oko wao kii dari jo je asin ile, aje ile, aje oko, won kii dari jo je
isu ogirisako, nisoju oso nisoju aje, ni atare nfi di tie ti ile fiikun, eyin
to laiye e ma fi owo buruku gbami mu o, ki e yonu si mi, ki eje ki n ri
temi se o. Ao ma fi foko mu. Odaju.
EDIJA TO LE
Aiku Alakan, Aiku Alagemo, aimoye eyo Ataare, Ewe Esinsin; Ao ko
Ataare le lori ninu igo pelu Alakan pelu Alagemo naa gba 7 days; Ao si
lo fi emuna ko Ataare na, ao da si ile Ile eni ti a ba fe ba ja.
OFO RE; Esinsin kii kere ko ma joni. Ao ba oogun na ro ejo ohun ti a fe
ko sele ninu Ile naa.

NOTE; ENIKENI TO BA FI OOGUN YI SE IKA, ILE YIO MU.ASE.


AYE MO JUBA!

S-ar putea să vă placă și