Sunteți pe pagina 1din 37

EGBO

IGI
IWOSAN
TI ILE

YORUBA
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OOGUN INU RIRUN


Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao
wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia
ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo
lo patapata lase edumare. O daju.

IDAKOLE(AMOKOLE)
Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e,
ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.

OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE


Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni
gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro
eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo
n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna
daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti
o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo
omi lasan.

OORU INU(INTERNAL HEAT)


Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan
leemeji lojumo.

OGUN GIRI.
Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba
juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti
oyinbo
ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo
na.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OOGUN IKO TO DAJU


Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan,
alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii
irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi
talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o!

ATOSI
odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu
da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta.
Odaju

AKOKORO
Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu
egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju
o.

EGBOGI GBOGBONISE
isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo
gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan.
Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa
die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi
agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo
arun.

EGBOGI JEDIJEDI (OGUN JEDIJEDI)


egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu.

OGUN STROKE
Omin igbin topo Dada ewe taba tutu ao gbo iwon OMI taba ri ninu
ewe yi ni iwon OMI igbin yi gbodo je pelu iwon oyun igan ao da
papo sinu igo tabi ike kan leyin ojo KEJI idi mimun haaaa ise ni sa
odaju bi iku iba eyin agba o
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN LAPALAPA
Ila Tutu Kan, Osun Die, Kanhun Bilala Die, Agun Pomo Ose Dd ,
Lilore: Leyin Igbati Abafi Apadi Haa Ibe Tan Afi Ose Naa Kan Omi
Fira Ibe

OGUN KOKORO ARA


ewe taba tutu, aidan, enu opiri, eru alamo, ao gun po, ao da die sinu
ipara wa, ao po iyoku mo ose dudu tabi eyikeyi, ao ma fi we.. Odara
lopolopo

FUN KOKORO ARA EYIKEYI


Ifo,eela, tabi lapa
Elo wa imi-ojo, e lo kuna bi elubo. E da kerosene die mo ki o mu
Dada, e lo atare meta mo. Ki e ma fi pa ibe.
Olorunlogbontan

OGU LAPALAPA
imiojo pelu eyin aro amri eyin aro yi Ni odo awon olose dudu amalo
imiojo yi si inu eyin aro ama bo oju lapalapa yi aoma fi ra oju re ti
aba ti we ton

OGUN IKO/COUGH
Oyin Gidi, osan wewe, ati adin eyan. Gbogbo idaji igo kid. Aodapo.
Fun omode sibi kan laro ati lale. Omona yio mabi tabi ya igbe.

AGBO MIMU FUN EHIN-DIDUN(BACK PAIN),ALE(MAN


POWER),ATI JEDIJEDI
Egbo-Egbesi Tutu,Egbo-Sapo Tutu,Muru Awon Hausa,Eso-
Abere(A O Gun Pepe).A O Wa Fi Soft Drink(COCA-COLA)
RE(Soak) Won Po Fun 3Days.A O Ma Mu Ni Araro Ki A To Jeun
Aro.OLOHUN NIKAN NI OLUWOSAN TODAJU.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGUNMU FUN GBOGBONISE ARUN INU ARA.


Enu-Opire,Isu-Baka,Iyere,Odidi-Atare Merin(4),Ose-Dudu Gidi
Ti Yoruba Die,Ako-Kanwun,Oro-Alago.A O Jo Won Po,A O Lo
Won Ebu Won Kuna-Dada.A O Wa Ma Fi OMI-LASAN Tabi OGI-
GBIGBONA(Hot Pap) Lo Ebu Na Ni Araro.OLOHUN NIKAN NI
OLUWOSAN TODAJU.

BACK PAIN
Ewe tagiri pelu kafura pelebe odidi kan, gigun ao fi ori ko ...ao ma fi
wo

AGBO JEDIJEDI TODAJU PA


Egbo egbesi a o ge kekeke ao yin odidi atare kan si a o fi sinap ki
fun ojo marun leyin ojo Karun odi mimu

AGBO FUN ORUN SLEEPING


1. ewe epin, ao gbo pelu omi ao da oti stout si, or ale gun kada stout
si. Ao se ao ma mu ni aro, osan ati ale.

2. Oyin igan Gidi, ao ma mu spoon meji lale leyin oje,

3. Egbo aso feyeje , ao re sinu omi tabi oti schnapps, ao ma mu sipi


merin tabi jubelo lalale

OGUN_DIABETES_TODAJU
Abere lopolopo,Aolo kunna dada, omi osan wewe, aoro omi osan yi
sinu igo abi white plastic, aoda abere yi sinu omi osan yi, aomamu ni
gaa si kan ni aaro, gas kan ni ale.

ADODUN_TIKOGBODO_GBA_NKAN_TI_LOWO_AHUN_O
KUNRIN_OR_OBINRIN.
Ora agilinti,Ewe kooko (cocoyam leaf) Ewe aluki,Aolo ewe koko
yen ati ewe aluki papo, aofi oyin gidi Po papo ma ora agilinti,
aomafi pa oko /obo loba eniti afejeki oti oribo takute
naaa,Hmmmm, ina koma oju eniti oda ooo....
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

RHEUMATISM
Agumun Aromonleegun ti amo
si Romathsim Akuko ti o ba je okunrin Abo adie to je Obinrin awa
yo gbogbo egun ti owa Lara adie na awa gun Mo egbo jebo aosa ti
yio gbe a ma Fi mu eko gbigbona

APORO
eso agbalumo die, enukopiye, kafura, Kanfo, aolo aoda sinu adin
eyan aoma mu

APORO
Ewe taba tutu, aogun aofun omi re sinu oronro malu, agbalagba yio
ma lo ni sibi meji, omode sibi kan

KI OMODE LE TETE RIN


aowa ese aparo mejeji aojo pelu odidi atare kan aofi singbere si
orun ese omo na, ese mejeji nio.

OYUN IJU
Epa iyan, eso bara, ewe akoko, ewe ekaja, iyo die, aofi omi nkan se
po ni agbo aoma mu ni cup kekere ni aro

ALEKO
Ikanrahun igbin, aosun ninu ina toba ti jona, aowa lo sugar pelu
kaunbilala, aoda papo mora won aoma fi mu eko tutu ni
WARAPA
omo aja kekere kan, opolo kan aojo papo, aoda obu otoyo odidi
mejo si Aowa po papo pelu adin, odi jije ? ? ?

LOW SPERM
E lo wa Ireke, Egbo Ogbolo, Sugar onikoro merin ki e ki ni agbo
pelu omi Ti o ba mo. Ki won ma mu ni e meta ni ojumo. Ki wo lo be
yen gba ko osu kan lai sunmo obinrin leyin na ki wo lo se ayewo a ti
wa ok.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO FUN JEDIJEDI ATI ALEKO


Epo Igi-Orira,Epo-Emi,Eso-Ebere,Kannafuru,
Emi-Gbegiri,Egbo-Akogun,Epo-Idin,Epo-Ogbogbo,
Eso-Boni,Epo-Oganwo,Egbo Aidan-Toro,Egbo-Gbonyingbonyin,
Epo-Okuku(A .o Ge Won Si Wewe),A o Wa Fi OMI- LASAN TABI
OTI-SINAPU RE(SOAK)
Won Po Fun 3Days.A o Ma MU Diedie.olorun lelesan,

OOGUN IKO TUBERCULOSIS


1.Atare
2. Ata ijosi
3. Aayu
4. Egbo Igi Guava gbigbe
5. Egbo Igi Cashew gbigbe
6. Alubosa Elewe
7. Ojere epo
8. Iyo
Ao lo 1 to 6 po ni ori olo gege bi a se ma nlo ata lori olo. Ao ge eran
maalu bi oni #500 tabi iye ti owo wa ka si mesan fun okurin, meje
fun obirin, ao gbe ojere epo ka ina lori adiro sugbon a ko ni je Ki o
gba o. Ti o ba ti gbona di e, ao da elo ti a lo lori olo si pelu eran ti a ti
ge. Ao je Ki o so papo fun igba di e Ki a to fi iyo si Ki o le ni adun. Ao
je ki o jina daada. Eni to ba ni arun yi nikan ni o leto lati je obe yi. Ko
si ohunje ti ko le fi je. Arun na yio poora pelu Ase Edumare.

DIABETES CURE INSULIN PLANT


(Costus igneus)
Costaceae plants are known as insulin plants because they can
lower the high blood sugar naturally. These plants grow in Asia and
South America and can also fight free radicals, destroy bacteria,
and act as a diuretic.

How to use
The leave must be chewed.
Pregnant or Nursing Mum stay away .
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

Also Drinking the insulin leaves boiling water will optimally work
to inject the natural insulin essence to reduce the level of blood
sugar.

It is called....
Yoruba = #Tete_Egun
Igbo = #Okpete
Hausa = #Kakizuwa
Efik = #Mbritem

FUN ENITI OBA NI OMO TUNTUN LOWO TABI ITOJU AWON


OMO WA.
1. OGUN TI AFIN WO OKA ORI FUN OMO TUNTUN.
Aowa ongo Ori isu
Ekuro oju ona die
Aojo papo Aoda sinu adin eyan aowa ma kan Omo naa Lori die die.

2. OGUN TI OMODE KOBA TETE RIN


Aowa
Panti tohu Lori kukute igi
Igo funfun tofo
Ose dudu
Aowa gun papo ao ko lose aowa kosi Inu Eku igo yoku yen.
Aoma Fi we Omo naa .
Pelu ogo Olohun Kia ni Omo naa yio ma Rin.

3. OGUN ASE ORI OYAN


Aowa Ewe Ailu
Okan owo eyo 9 fun okunrin 7 fun obinrin
Ose dudu
Aogun papo aowa mafi we OYAN naa die die. Pelu ogo Olohun
Omo naa yio gba omu naa. Beeni owulo fun obinrin ti OYAN re
koba yo Omi omu daadaa.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

4. OGUN BI OMODE BAFE HU EYIN OKE.


Aowa
Omunu ewe okika die
Ao ko soju owo eyo.
Aoma Fi kinri enu Omo naa. Ehin naa yio wole ni kiakia.
NB..
Ewe ekika awon nkan pe ni EWE IYEYE.

DIDE ABIKU MOLE.


Aowa
Eso ejinrin pupo
Kerengbe tofo si oju ona odo
Ewe kehinsorun
Ewe dagunro
Odidi atare nla kan
Aojo papo aofi die sin gbere kan si ese mejeji ATI owo mejeji Omo
naa.
Aowa ran die ni igbadi awo dudu si ni idi. Yio ma fisi idi titi di Odun
meji pere.
Pelu ogo Olohun Omo naa yio kuro ni ABIKU yio di alaaye...

OGUN TI OMO BAKO OYAN


Aowa
Agogo Enu eye Agbe
Egbo igi obi (kola nut)
Aowa lowan papo aomafi pa Ori OYAN.
Kia ni yio gba Oyan naa.
Lati owo oludasile egbe

OKO_TI_KOKIN_LETAN_TOBAFE_SE_HUNNN
Poporo oka baba,
Bara 1,
Epa ikun
Aoge gbogbore si wewe, aokosi inu Igo, aobu HOT Lee Lori, aoma
mu die die,
Hmmmm, oko na yiole ti gbogbo isan arare yio jade tan daradara,
kosi tunni tete da enu kole.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

APAGUN
EGBO GBOGBONISE,,EGBO AKO IBEPE,,ERUN
ALAMO,,ALUBOSA OLOWO,,YANKO,,AO GE GBOGBO
EGBOGI YISI WEWE,AO GI SINU IGO,AO DA YANKO SI
LORI,,MIMU LATIJO KETA LO,,SIBI KAN PERE...

OGUN ITO SUGAR TODAGU


tested and trusted: egbo ipeta ao sa wewe ao ko sinu igo kan ao wa
da omi osan wewe original si ao file fun bi ojo meta Kofi toro Dada
ao ma wa yomu, to mu pe ose kan eni kolose test odamiloju.

NARUN OLOJU SUSU


Afomo okuta, ao lo ti yio da bi tiro, ewe eyin olobe to po, alubosa
elewe to po, ata dudu topo, kahun bilala to po, epo igi pandoro to po,
epo igi isin to po, ao gun papo ao mafi mu eko gbi gbona

OGUN IPAKE TABI KUNNU KUNODE


Igi oro agogo, igi oro adete ati ewe re, topo, alubosa onisu topo,
kanhun bilala topo, obuotoyo topo, iyo obe topo, ao jo oro mejeji
papo, ao lo kanhun, obuotoyo, ati iyo obe, ao lo po daada mo eyi
toku, ao mo bu die die da sinu omi orombo tabi ogogoro, mimu 3x
daily

Ewe rekureku weere topo, odidi atare kan, jijo po, ao popo mo ori,
lila 3x daily

Eso bonni, lilo kunna daada, pipo die mo ori, ao mo fi pa oju ipake
na, ao ebu toku sinu schnapp, mimu ni gas kookan 3x daily

Oro agogo topo, oro adete, ibaka topo, teyo die, isu alubosa topo,
odidi atare mewa, enu opiye, ao jo papo, ao fi soto, kanhun bilala
topo, obuotoyo topo, etu ibon topo, ao lo gbogbo re papo, ao da papo
mo ogun ti ajo yi, ao ro pamo
LILORE :- Ao ma to sibi ogun yi kan sinu cup, ao tu oti schnapp le
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

lori ao ro papo, yio ma mu bee 3x daily, gbogbo re ni yio yo die die ti


yio fi yo tan pata pata

OGUN ARAN KINISA


Alubosa Elewe Ogiri Ijebu Egbo Ijaganyin Aolopo Moalubosa
Elewe Yen Aopomo Ogiri Yen Ao Fi Adin Eyan Din Kojina Dada Ao
Maropo Laro Yio Ma Yo Sibi Kan Mu

OGUN ARAN
Ewe Taba Gidi Eepo Atorin Dudu Aoge Wewe Sinu Kolobo Aobu
Omisi Aogbe Kana Aose Lati Aro Titi Di Ago 12 Osan Tiaba
Wasokale Aoju Kanwun Die Toba Tutu Aoro Sinu Igo Olomori Yio
Ma Mu Ni Igasi Kan Ojo Marun Marun, *hmmm Ise Ni*

OGUN ATOGBE TABI KI A MA TOJU LALE (TO PREVENT


URINATING MORE THAN TWO TIMES OVERNIGHT).*
Ewe yanrin toopo aogun kuna dada .laini omi.aowa
fun omi ibe Dede omi no ni omi osan wewe yio
je gas kokan laro lale

EDA
je Aarun to ma nse Obinrin to ba ti balaga daada ati pe kii se
Okunrin rara o=Sugbon gbogbo iwadii ti awon Onimo ijinle si nse
titi doni fi han gbangba pe ko si Oogun Oyinbo to kajue yato si
Oogun ibile wa”Aarun yii kii jeki Obinrin loyun ati pe ko si irufe
obinrin ti kole kolu`yaala Omidan tabi Adelebo to si ma ndena
Oyun nini lai se familii planii{feto somo bibi o}Oruko ti gbogbo
yoruba mo`Arun yi si ni Èdà
Sugbon laatari Orisirisi Ona to ngba ba awon Obinrin finra ni won
se ba yaa Oruko re sotooto”Bi Eda _Naaro”___Eda Duubule
abbl....
iwadi koiti fi idi mule pato ohun to nfa Arun yi Sugbon bi Aarun naa
ba se pe si lara Obinrin ni o ma nlagbara si”Nitorina ni o se ma nso
awon Onisegun ibile di Eeke tabi Opuro.....
Ti Okunrin ati Obinrin ba ni ibalopo"Loju ese nibe ni ukan
omokunrin ti a mosii Aato{sperm}ma daa pada tabi Nigbati
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

Obinrin na ba dide duro'ta npe ni Eda inaaro”Sugbon ti Elomiran


le je pe lehin Ojo keta lo to ma daa pada o=Awon iwadi keekeke
fihan wa pe ki awon Obinrin Sora fun unkan Alaadun jije tabi
mimu Eleridodo bii kokakola{coke}ati bbl;opolopo obinrin lo ma
nsope ti oun ko baiti mu awon unkan Aladidun yi!Oun o mo`bo se
unse oun=paapa nigbati a ba ti wa ni Olomoge ni ki a ti ma kilo fun
awon omo wa Obinrin o=

*Ona Abayo* :-Ti a ba ni awon omo ti o ti balaga daada tabi ti ojo


ori re ti nto omo odun meedogun soke tabi ti o ti nse unkan osu re=
*E lo ja Ewe Ewuro{Bitter Leaf}A o gboo Pelu Krest tabi Schwepps
igo bi meji tabi meta”A o gboo daada ninu Abo tabi ike ti o
mo`daada”mimu ni Gaasi kokan ni Owuro kutukutu ki won to
jeun lo dara ju o*
{O tan lenu”O ku sikun Agba}

OOGUN EDAA TO CONFIRMED


{1}Ojele ewe idagbaa, a o lo kuna dada, a o fi ogede iboyin se Asaroo
, a o faa ewe ti a lo yi si , a o se jina Pelu epo ati ata sugbon a o ni fi
maggi si o, a o ma je die die.

{2}A o lo jaa ewe jeleruberun Nigbati o ba panudee lale laisoro kato


ko delee, a o lo laseje , a o fi eja aro pelu Ring kan sii, a o se jina lepo
niiyo, a o je , a o ma fii ring na sowo wa. Sugbon ihoho la o lo egbogi
yi lai fohun nidi e rara o.
*Tested_confirm*

EGBO ADAJINA
Epo orogbo, ekute ti aba ri ni oju ma ti a ko mo nkan topa, ao sagbe,
ao waa gun po mo epo orogbo naa, ao ma yosi oju egbo naa.
NB:- Egbo naa yio jina laarin ojo mefa.

OGUN KI OROGUN MEJI NIFE ARAWON


Ori Ewure ti won fi se etutu, ao fi ada pin ori na si meji ti ko ni ge
dele, ao ko ewe Odan Abalaiye sarin meji ori na, ao ju odindin atare
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

kan si, ao jo ao ma fun awon iyawo mejeji na la. Won yio nife ara
won, won koni ja rara. Odajau

AGBO IGBE EJE TABI OGBE INU


Ewe Idoro, ao gbo ao fi ori die si, ao gbe le lan yio gbona foro, enina
yio ma mu. Odaju.
Oluwakoremide

OGUN TI AFI NLA ODI LOHUN


Ori Odidere 2, Ori Awoko meji, Odindi atare kan, ao jo po ao gba
Epo pupa lori ina ao da sinure yio mala. Odaju

2. Ewe Ela, Ahon Ofafa, odindi atare kan ao jo papo ao da sinu oyin
igan yio mala. Odaju

3. Ewe Ela odindin atare kan, ao jo po ao ma da sinu Agogo ao bu


omi Isu si, yio mu, ao malu Agogo na si leti. Odaju
Oluwakoremide.

OSE AJEGUN
Ifun Ako Alangba, ao gun ao fi ose po ao ko opolopo oruka irin sinu
kokoradu agbon ao ko ose na le lori, ao ma fi oss na fo owo(hand),
eniti aba fun ni oruka yen ogun yio ma je fun o hun na. Odaju
Oluwakoremide

AGBO AKO JEDIJEDI TODAJU


Bara kan, ao ge kekeke, Akogun, Muru, Epakun, ao ko gbogbo re
sinu ike tabi Igo totobi ao bu omi ti o ba mo dada le lori, leyin ojo
keta ao ma mu ni ekan lararo.
Oluwakoremide

AGUNMU INU GBIGBONA


Iresile ewe asunwon, Iyere, Eru Awoka, Imi Orun, ao gun yio kuna
dada ao ma fi mu eko gbigbona lale laro. Odaju
Oluwakoremide
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO FUN ENITI OBA SANRAJU TABI KO MA LA O GUN


NIGBA GBOGBO
Egbon Ifon tutu, ao ge wewe sinu ikoko nla, ao bu omi si, tio ba di
ojo keta ao mamu, ao ma we. Odaju
Oluwakoremidex

OGUN HYPERTENSIN (EJE RIRU)


(aowa Ododo Ori Ako Igi Ibepe Aodasinun Omin Tiwan Bafise Iru
Aofi Sibe Fun 4days After 4days Aomamun Nin Aro Ati Ale Nigbati
Aobafimun Fun Ojo Meje Pelu Ase Olorun Yioti Kuro Nibe

OOGUN OGBE INU (ULCER)


Ao wa efo gbure ..ao gbo daada ti yio MUN bi igbati won ja
ewedu..ao gbe sori ina..ao ni fi omi sio..
Ao da gari si ti obati gbona daada..ao fi teba...ao wafi eba naa je obe
toba wuwa...walahi walahi walahi DANWO...kosi bi ulcer naa se pe
Lara to..

OGUN NANRUN INUN ARA


(aowa Ewe Apasa Tiwanhunpe Nin Ewe Imin Esu Aoja Ewe Nan
Aodasinun Omin Aose Bi Enin Se Efo Aowa Lo Ata Si Aofiro Efo
Nan Pelu Iru Aofi Efo Nan Je Eko Aowa Ja Eso Ori Imin Esu Nan
Aowa Sa Ti Yiogbe Aowa Gun Papo Aowa Dasinun Epo Ogere
Aomafi Ra Oju Kokoro Tioba Sujade Lara Wa Pelu Agbara
Olorun Gbogbo Nanru Tiobawa Ninun Eje Gbogbo Re Nin Yioku

ALASE FUN OBINRIN


Eepo Osan Wewe,orogbo Gbigbe Merin,odidi Atare Kan,alo
Kanhun,egbo Inabiri,ao Jo Papo Dada, Obinrin Naa Yio Ma Fi Eko
Gbigbona Lo.

ABIWERE
Ewe Odundun,ao Lo Yio Kunna Dada,ao Fi Ori Po Papo
Dada,obinrin Naa,yio Ma Fi Wo Ikun Re Wa Si Isale Odaju.
Stroke(roparose)
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

Alubosa Ayu,ao Ge Sinu Igo,ao Wa Fi Omi Igbin Si,ao Ma Mu Ni


Sibi Meji Fun Agbalagba,sibi Kan Fun Omode Lojojumo,olohun
Koni Fi Stroke Ba Wa Ja Oo.

FUN INU RIRUN


Akogun,ao Re Sinu Igo Kan,ao Fi Omi Tutu Ki Lagbo,ao Ma Mu Ni
Sibi Kookan Lojojumo

JEDIJEDI
Ewe Efinrin,ewe Owu Akese,ewe Ewuro,ao Wa Omi Tutu Gbo Pelu
Iyo Die,mimu Larolale.

IDI YIYO
Ao Fa Paki Ege(cassava) Olomo Kan Tu,ako Ni Je Ki O Kan
Mole,ao Wa Jo Paki Naa Pelu Iyepe Arare Ati Odidi Atare Kan,ao
Ma Fi Foko Tutu Mu.

OGUN IKO
Egbo Ipete,egbo Ifon,ao Ge Kekeke Sinu Ike Ragolisi,ao Bu Iyo Die
Si,ao Wa Tu Omi Ororo Maalusi,ao Wa Gbe Pamo Fun Ojo
Meta,ao Ma Mu Ni Sibi Kankan.

OGUN IKO IFE/AWUGBE (ASHTMA OR TB)


Ewu Ogan, Obu Otoyo Adin Dudu.
Ao Da Ewu Ogan Yi Sinu Ikoko Oru Ti A O Sun Ti Yoo Di Eru, Ti O
Ba Ti Fe Dudu Tan Ao Fi Obu Oto Yo Si Ni Iwon Ba, Ao Je Ki Ewu
Ogan Ti Ati Jo Yen Ki O Tutu, A O Wa Bu Adin Si, Eni Na Yoo Ma
Mu Ni Sibi Kankan Ni Araaro.

QUICK EJACULATION.
Orogbo, obi gbanja,etu ibon,ako okuta,esuru funfun,ege tia fi ngun
iyan,ogede agbagba dudu,agbado ,iyere,ao fi sugar die si, ao gun
po,ao ma fi fo eko tutu mu.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO INU IGO FUN ALE OKUNRIN* (MAN POWER)


Itaku gbonyingbonyin,Itaku eruju,ao ge mejeji sinu igo kan, ao wa
ro 7up si tabi oti oyinbo, gaasi kokan ni ojojumu.
2.Itaku gbonyingbonyin, Itaku Igongon,Itaku Aka,Itaku
idiapata,Itaku osun,Itaku ogbolo,Egbo Asunrun oyinbo,Egbo
Asunrun yoruba, Ako okuta were funfun mesan,Eso Abere
mewa,Iyere die,Konnofuru die. Ao ko okuta wewe pelu awon nkan
toku yen papo sinu igo, ao da oti oyinbo si, ao ma mu diedie. Odaju.
Omode lo nse mi ooo.

OGUN IGBEBI FUN OBINRIN TO DE ORI IKUNLE.


Ojo ti agbami ojo ba ro, ao lo si ona oko tabi odo, ao mu igo ofifo tabi
ado ato lowo, ao ri awon ekolo dudu kan, awon miran npe ni kola
tabi olooji, o ni pon to ika, o we lorun bi okoto, ao fi owo lale siwaju
ekolo na, ao fi igo tabi ato yen niwaju re, ao je ko bo sile fun rare, ao
ko opolopo atare le lori, to ba di ehin ojo keje ti obinrin na ba de ori
ikunle ao fun ni mesan tabi mewa ninu atare na, wipe kio je pelu
omi gbona idaji tombila.

OGUN ALASE TI OBINRIN KO BARI NKAN OSU RE.


Iye aluko, ikoide, poporo ehin oka baba,iyo die, osun buke,ewe
owu,epo amuje,egbo oruwo ati egbo lali,ao gun po,obinrin na yo ma
fi mu eko gbona.

OGUN ILE TUTU


Esan,epo ose,eru,aidan,egbo elu,egbo about,alubosa elewe,ao se ni
agbo daadaa,ao fun omo naa mu.ao si ma fi we lati orun de le.

AGUNMU IBA TODAJU


Epo pandoro awon miran npe ni iyan tabi amuyan,ata dudu,egbo
oruwo,alubosa elewe,kanhun,eru,ewe ewuro ati iyo.ao gun po
daadaa,ao ma fi mu eko gbona...Odaju.....

OGUN ITO SUGAR DIABETICE


ao wa ako kahun bulala ,epo oronbo ,ewe koropo,obu otoyo ,ose
dudu ajo gbogbo kini yi papo pelu ose dudu ao lo ao mon fi orombo
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

lo laro ati lale......dan wo kio fun mi laboo abara mun pelu ase
olorun oo

OGUN ATOSI
ao sun bara ni ina tio fi ro dada ao wa be epo re danu ao wa ge bara
yi wewe ao fun omire sibi kan ao wa da sugar si omire ao tun da
orombo dede omi bara yi sii ao mon mun ni sibi kan larin ijomete
meta ..........odaju gan nioo abara mun pelu ase olodu mare

AGBO ARAN
eyikeyi tabi alepe agbo gbogbo aran, Egbo sapo Egbo ifon Egbo
tude ao fi omi re ao mamu diedie laro ati lale
2.Egbo arunpale ao fi omi osanwewe re ao mamu ni gasi kokan
*Ogbe nu (hulcer)* ogede agbagba dudu ao ge bi Eni pe afefi din
dodo ao wa sa si Abe ile tabi inu yara tobagbe dada aolo kunna dada
ao mafi wara tabi milk lo siwaju ki ato jeun aro

OGUN HYPERTENSION,
eso pandoro ao sa ti yio gbe dada ao wa lo kunna dada ao mafi mu
eko gbigbona sun lalale

OGUN EJE RURU/H.B.P


Ao Ja Eso Isin Toba Pon Daadaa,ao Jo Pelu Odindi Atare Kan,ao
Maa Fi Coca Cola Loo Daaadaa.

OGUN ITO SUGAR


E o wa efo gbagba ti yo pon die,omidun lafise pelu kanu bilala die
tobati jina dada ,ero si inu kegi kan efi suger oni koro mefa si
,tobadi ojo keji eni ye yo bere sinu mu odaju gan motise fun opo
eniyan ri,,,aisan koni fi ago ara wa se bugbe o ,,

OOGUN IKO TUBERCULOSIS


1.Atare
2. Ata ijosi
3. Aayu
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

4. Egbo Igi Guava gbigbe


5. Egbo Igi Cashew gbigbe
6. Alubosa Elewe
7. Ojere epo
8. Iyo
Ao lo 1 to 6 po ni ori olo gege bi a se ma nlo ata lori olo. Ao ge eran
maalu bi oni #500 tabi iye ti owo wa ka si mesan fun okurin, meje
fun obirin, ao gbe ojere epo ka ina lori adiro sugbon a ko ni je Ki o
gba o. Ti o ba ti gbona di e, ao da elo ti a lo lori olo si pelu eran ti a ti
ge. Ao je Ki o so papo fun igba di e Ki a to fi iyo si Ki o le ni adun. Ao
je ki o jina daada. Eni to ba ni arun yi nikan ni o leto lati je obe yi. Ko
si ohunje ti ko le fi je. Arun na yio poora pelu Ase Edumare.

OGUN MAJELE
Inje Emo Pe Ito Idiwa Nsise Fun Mojele Ti Abatimope Majele Laje
Aoto Sinu Cup Kan Aogbemu Lesekese Gbogbo E Lama Po Pada
Odaju

OGUN ORI FIFO


Aoja Ewe Ata Die Aobu Iyo Die Si Ao Fowora Awafun Omi Re Si
Arin Ewe Nan Efori Nan Yiolo Lesekese

OGUN TI EJO BABU EYAN JE


Aowa Ata Ijosi Eyokan Awage Si Meji Amafipa Oju Ibiti Ejo Gbe
Buyanje Yen Yiopa Gbogbo Oro Re

OGUN TI ALABOYUN KOBATETE RI OMO BI NI OJO


IKUNLE
E Wo Agbara Ewedu Ti Ao Kasi Inkan Toun Sise Fun Alaboyun Ao
Ja Ewedu Tiyiopo Die Ao Fi Omi Lasan Gbo Ao Fun Alaboyun Nan
Mu Yio Bimo Lesekese Ni Agbara Olorun.

OGUN KOKORO INU EJE/INARUN/KURUNA


Ewe Ailu Gbigbe Yio Po Ao Ko Sinu Ike Kan Kie Da Adieyan Lelori
Yiyo Mu Sibi Meji Laaro Meji Lale,.... Fun Kuruna Eo Ma Fi Para
Ara Elomi Le Ma Gbona leyin lilo ogun yi kosi nkankan
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

IFO ATI PIMPLES...


Imin ojo, omo atare, etu original, ao lo won kunna lotooto, fun
kokoro kuruna tabi lapalapa tabi pimples ao po lori ao ma fi pa, fun
ifo ao bu si kerosene, ao ma fi pa leyin ojo keta ifo yio dahun
igbagbe.... But ao ni fi ori si ti eyiti aba fe lo fun ifo ooo

EGBE (TUBACULUSIS)
Ogede Odo, Okan Malu Tio Womi, Ao Ge Ogede Yen Wewe, Ao
Gbe Lo Si Odo Eran, Okan Maalu Tosinso Ni Ao Ra , Ao Wa So
Ikokomagbo Kan, Ao Wa Da Ogede Odo Yen Sori Okan Maalu Yen,
Ao Wa Da Omi Si Nibe. Ao Gbe Lo Sile. Ao Se Dada Lori Ina Ti Aba
Ti Dele...mimu Fun Alaisan Naa..odaju

EFORI TULU
Akan (alakan) Aruga Oye Kan, Ao Gun Laaye, Ao Fi Ose Ko, Ao Fi
Ejirin Se Kainkan Re, Ao Fi Fo Ori Sinu Bafu Kan, Ao Lo Da Si
Orita.

OGBE INU / ULCER


Epo Idin, Ao Re Ni Agbo Tutu Pelu Omi Tomo, Mimu Laro, Losan,
Lale. ..2.. Ao Ra Eko Elewe, Ao Bo Ewe Ara Re, Ao Maa Fi Eko Yen
Kan Oyin Igan, Ao Ma Je Larokutu. Ikilo: Eni Naa Ko Gbodo Ti
Ewe Je. ( Akii Ti Ewe Eko Yen Je )

ALEKO
Ikumu Ojia, Orogbo Mewa 10, Atare Mefa 6, Ao Gun Po , Ao Sa
Gbe, Lilo Pelu Oyin Die Die. Try it please

ASEJE ROPAROSE / STROKE


Ewe Turuturu Tikoti Tuka (sonso), Ao Lo Mo Iyere Ti Koniye, Ao
Wa Da Ogogoro Tabi Schnapps Sinu Ikoko Tuntun Kan, Ao Wa Da
Awon Elo Ti Alo Yi Si, Ao Wa Ju Eja Aro Aye Si Lori Ina, Ao Gbe
Nkan Le Ikoko Yen Ooo. Alaisan Naa Yio Maa Je Diedie Lojojumo
Fun Ose Kan . Odaju
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

CRONIC STROKE
Eje Ako Pepeye Ao Damo Hot, Ao Mix Re Daadaa. Mimu Lemeta
Lojumo

MINI STROKE
Omi Odo Tobamo Daada, Oa Fi Obuotoyo Si, Mimu Lemeta
Lojumo.

OGUN TAIPHOID
Ewe.oparun Tutu, Ewe Ehinolobe Ao Se Lagbo Ti Yio Jina Dada Ao
Mu Ni Emeta Lojumo Sugbon Toba Ki Enia Male Yio Sodi Omi
Mimu Re Odaju

OGUN ITO SUGAR


Ewe Ewuro.lopolopo Ao Gun Lodo Ao Wafi Omi Gallonu Kan Se
Dada Ao Wa Jo Kuku Agbado Yio Po Bi 6 Or 8 Ao Sun Ninu Ina Ao
Lokunna Dada Ohun Lao Mabu Sikan Sinu Cup Ogun Yii Kan Ao
Mamu Laro Lale Odaju.

OGUN AKOKORO
lati owo. Khalipha Qoseem Faduagbemi. Egbo Orin, igi
ataa, taba gidi, I'm Osun, kanhun bilala, omi ogi ni ao fi se dada, ao
ma di si enu Nigba gbogbo.

OGUN INU RIRUN


.lati Owo khalpha Faduagbemi. Oronro malu tabi Oronro ejo oka,
ao Lo opolopo atare si di ojo keje, bi inu ba nrun eniyan, ao je ninu
atare yen. Odaju gan

OGUN ILE TUTU


Esan, epo oshe, eru, Aidan, egbo elu, egbo abo, alubosa elewe, ao se
ni agbo dada, ao eni na mu, yio si mafi we lati Orun wa si ile

OGUN OYI OJU TIO DAJU


Epo awusa, ori eiye etu, ewe alupaida, ota inu iroko, odidi atare
kan, aojo papo aoda si inu epo pupa ao mala. Nigba ku gba. Odaju
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN IKO
Epo iyeye, igi teteregun, ewe Omisinmisin, sugar die, ao ki ni agbo
äo se, Odi mimu, Omode sibi kan, agbalagba sibi meji. Odaju.

ITO SUGAR
Ewe ewuro,ewe iyalode funfun,ewe eyin olobe,ewe efinrin,ao gun
mererin po ao sa tiyio GBE ao watun gun ni agunmu tobagbe
tan.,ao mafi mu ekogbona...pelu ogo olohun ao nigburo ntinje ito
sugar Na mo taba dunnu mo nililo

OGUN ATOSI TIO DAJU.


Ao toju bara Aoko egusi inu e kuro, aowa ge wewe . Ao wa ogidi
Emu tabi omi orombo wewe, ao ko bara tia ge wewe yen si inu Emu
ogidi yen tabi omi orombo wewe pelu kanhun bilala di ojo keta Kia
to mamu. Osise gan. Odaju.

OGUN KOKORO OMU OBINRIN


Ewe egele tabi mafowokan omo mi, ireke, ogede wewe tikogbo,
eru,epo pupa die, ao fi omi orombo wewe si, ao wa se ao mafi we
omu na, enina Asi mamu. Odaju. GBOGBO agbara olohun
LONI. Faduagbemi oluwa.

OGUN AKANDU
Egbo inabiri aolo kunna daada ao wa lemo ibiti o bati mu wa ao fi
aso kan di ao wa ma fira ina

OGUN ENI TO BA SANRA JU


Epo eyin agbado, osan wewe,ao se pelu omi lasn,ki won mamun ni
tombila kankan ni emeta lojumo

IDAKOLE
==============
Ori ejo sebe nla kan,ao gun yio kunna dada ao tun gun ogede dudu
gbigbe kunna ,ao da mejeji po
ao wa lo suga oni koro bi mejo mo ao ma fi mun ogi gbigbona.
I: E je ki nfi eleyi fun gbogbo awan ti eje ruru nda laamun
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN HYEPETENSIO
omi agbon cup meji,omi igbin cup 2,0yin igan cup kma ,igo oti cup
meji ao mix re papo a da papo
sinu keg kan ao mayomun ni gasinkan laro ati lale,very effective.

OOGUN INU RIRUN


Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao
wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi
kafi omi gbigbona loi. Inu rirun naa yo lo patapata lase edumare. O
daju.

OGUN ENI TO BA SANRA JU


Epo eyin agbado,osan wewe,ao se pelu omi lasn,ki won mamun ni
tombila kankan ni emeta lojumo

IDAKOLE

Ori ejo sebe nla kan,ao gun yio kunna dada ao tun gun ogede dudu
gbigbe kunna ,ao da mejeji po
ao wa lo suga oni koro bi mejo mo ao ma fi mun ogi gbigbona.

OGUN IKO TO DAJU KODA KI IKO NAA LE KOLE MUN JU


EMETA LO.*
Elowa epo ori adi ati eru alamon ewa se papo ko jina dada.
Eyo sibi kan koma lo ni spoon kokan laro losan lale,

OGUN ULCER
aolo ogede agbagba dudu mewa kunna Dada aore sinu omi liter
merin fun ojo merin leyin ojo kerin ao mamu ni gaasi kokan tio bati
ku wakati kan tiama jeun aaro ati ale titi yio fi lo olorun aje kio
bawa lara muo

OYUN IJU FIBROID


Ao ge eso pandoro ati ibepe dudu si wewe ao lo obuotoyo kunna
pelu kaun bilala die omi osan wewe (two liters) aoda eto yi sinu re.
Ao si ju ose dudu (#50) kan sinu re ao fi sile fun ojo kan lilo re idaji
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA
cup kan ale cup kan yio bawa lara mu pelu ogo olorun

OGUN ARUNMOLEGUN
Ao fi liter omi osan were kan gbo ewe guava topo die ao sifi ase se
lilore ao waje carrot laaro kutukutu ao si mu eto yi lelori fun ojo
marun olorun aje kobawa laramu oooo

AGBO TI ENIA BANRU TONGBE


Epo Igi Emi Gidi, ,epo Igi Igba, ,egbo Ifon, ,,egbotude ,okuta
Ako7/9 ,fun Tako /abo, ,a O Se Pelu Omi Tiyi O Ho Dada ,idire
Kogbodo Kanlemo, ,ti Aba Tifemu A O Wa Bu Sinu Abo Kogbona
Ferefe,aowamu

AGBO NARUN
Wash your stomach first, Ewe lapalapa funfun, ise lagbo, ewa ose
dudu lati mafi we. Stop eating sugar, reke, aadun etc till it stop

AGBO MIMU FUN INU-RIRUN* GBOGBONISE;


Alubosa-Elewe To Po Die (A o ge si wewe),Ayu Eyo Kan(1).A o Wa
Fi OMI-OSAN WEWE(Lime-Water) Re(soak) Won Po Fun
3days,A o Ma Mu Diedie

OGUN INU RIRUN TOSISE TAARA


Aowa Eso Akerejupon. Eso Abeere. Aolo. Won Kuna. Aopomose
Dudu. Aowa Fun Omin Inu Ewe Ewuro. Aofipo Ose Yi. Aotun Fi
Oronro Malu Po. Tio Se Mun. Aomawamun. Ni Sibi Kookan

OOGUN INU RIRUN


Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao
wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi
kafi omi gbigbona loi. Inu rirun naa yo lo patapata lase edumare. O
daju.

IWOSAN FUN INU RIRUN


Ao waa ewe Akoko ao gbo pelu kan bilala ao mun walahi inu naa
yio poraaa ni bi ogo ba nje ti Olohun oba
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN ARAN INU


Aran ma n je ki ounje tete da lara eniyan, eyi si wa lara iwulo re si
ara eniyan. Sugbon ti aran ba po lara, o tun le fa akoba. Idi ni yii to
fi ye ka dena opolopo aran ni ago ara wa.
Eroja: Ewe dongoyaro (Neem)ati osan wewe (Lime Juice)
Ipese: A ma gbo ewe dongoyaro mo ara won, leyin eyi la ma fun osan
wewe bi mewaa sinu re.
Lilo: Sibi ijeun kan ni aaro ati ni asale ti a ba ti fe sun. To ba je
omode ti ojo ori re ko ti ju odun marun-un lo, sibi omode kan laaro
ati lale ni fun un

OGUN ARAN GINISA


Aran Yi Mahun Ba Oyun Je Gidi Lara Obirin...
Eepo Ipeta..isu Agba..egbo Seyo..etu Ibon Ojuda Die.. Kahun
Bilala Die Eru Alamo Die. Ata Pupa Idaji Ekunwo Kan..alubosa
Elewe Kopo Die.. Aogun Gbogbore Po, A O Sagbe To Ba Gbetan
Atun Wa Tunlo Dada Ti Yo Kuna Obirin Na Amafi Mu Eko
Gbigbona Larolaro

AGUNMU FUN ARA LILE(STRONG BODY)


Eku-Asin Gbigbe Meta(3),Obi Mewa(10),Iseta,Orogbo
Mewa(10),Odidi-Atare Mewa(10),Egbo-Ifon To Po Die,Ako-
Kanwun.A O Gun Won Po Kuna-Dada.A O Wa Ma Fi Ebu Na Mu
OGI-GBIGBONA(Hot-Pap)Dede.OLOHUN NIKAN NI
OLUWOSAN TODAJU.

AGBO WIWE FUN INARUN(NESTLE)


Egbo-Iyere To Po,Egbo Igi-Ayire Nla, Eru To Po.A O Wa Fi OMI-
LASAN(Ordinary-Water) SE(Boil)Won Po Jina-Dada.A O Wa Ma
Fi Omi-Agbo Na WE(Bath) Ni Ojo-Ketaketa(Every 3-
3Days).OLOHUN NIKAN NI OLUWOSAN TODAJU.

ORUKO RE NI PEAR*
_E FE SORO NIPA KORO INU RE_

Dí?Ì lára ìwúlòo kóró inú èso pear yìí ni 'w?n


Ì yí
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

(a little benefit of the pear seed are):

Ì ?tÌ í : a cleanser
Af?d

AláruÌn-un ?kàn, j?j?r? : heart problem cure and cancer cure &
prevention

Adín ìgb?ì gbuuro kuÌ: diarrhea stopper

Kóró inú èso pear p?lÌ ú dáa fún alát?sÌ ì – the seed is also good for
persons with toilet infections,

?l?gì b?ì inú - ulcer, and aláruÌn-un ìbálòp?Ì – sexually transmitted


disease.

After eating j? the soft f?lì ?fì ?lì ?ì


edible part, the seed kóróo will be dried gb?, blended l?Ì ?ì fine
kúnná
and made into powder ebu called àgúnmu.

BAYII NI A SE LE SE IWOSAN SONGUN-SOGUN, AWOKA


ARA ATI LAKUREGBE*

*Eroja* : Koro pear oyinbo nla meje, adin dudu.


Ipese: A ma sa koro pear naa sinu oorun ti yoo gbe daada. Leyin eyi
ni a ma lo ti yoo kunna daada. Ti a ba se eyi tan, a da adin dudu si i.
*Lilo* : A ma la sibi kan leemeta lojumo. Eyi tunmo si wi pe, a ma la
sibi kan laaro, sibi kan losan ati lale. Bakan naa ni a ma fi para
lojoojumo.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO TOO SISE FUN AKO JEDIJEDI PAJAPAJA ATI AILE SE


DEDE OMO OKUNRIN

TI eyan OSI YAA IDOTI INU DANU


Bara , EPAKUN, obukotuyo , Ati 7up Ao fi obukotuyo yen die
tele..ao bee bara YIN ao ko gbogbo egusi inu re kuro ao kesi
weweAOkosiinu ike Eva NLA ao ke epakun na si AO wada7up si
fun ojo meta Leyin ojo keta ao ma mu ni gasi kankan ni ojo keta
keta..

OGUN JEDIJEDI ATI OPA EYIN


Ao wa ewe yunyun die ati ewe taba eyo kan ao gbo papo lai fi omi si
ao mun sibi meta laro ati sibi meta ni ale .pelu agbara olohun opari

FOR GOOD ERECTION*MALAIKA


Slice three big onions add small water then cock for 10-15 minutes
when the onion is soft, extract the juice, mix with HONEY of the
same quantity, then cook again for 5-10 minutes. Then store it in a
bottle when it cools 2-3 spoons in the morning and evening after
meal.

OGUN EYIN DUNDUN


Igba Eyin Ijapa Okun Ti Won Nlo Igibolatioko Pelu Ikereretiwon
Filo Odindiatarekan Aojopo Aopo Ninu Remose Fun
Wiweaomalaeyitoku

INU RIRUN
Lo Ewuro po mo Oyin ma lo sibi meji lehin onje ale.

EGBO
Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo na.

EYIN OMODE
Oyin Igan ati Omi Osan wewe mon ara won. Ki o si fun Omo na ni
sibi kan lemeji lojumo lehin onje.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

IKO IFE (TUBERCULUS)


Lo Atare, Ayu, Iyo ati Orogbo pelu O yin Igan sinu Igo. Agba sibi
meji ni igba meta lojumo

AIRI ORUN SUN


Maa mu Oyin Igan sun. Sibi meji lalale.

AILERA NINU OSU OBINRIN


Nkan osu to nse segesege tabi to dudu (STOMACHPAIN) Lo sibi
Oyin Merinmerin ni Emerin lojumo.

ARONMOLEGUN
Lo Ewuro po mo oyin Igan fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo sibi meji li
ojojumo ni owuro kutukutu.

AKANDUN TABI EEWO(BOIL)


Lo Ewa ati Kaun po mo Oyin Igan. Ma fira ibe.

OGBE INU(ULCER)
Maa mu sibi Oyin meta ni owuro kutukutu ni wakati kan ki o to
jeun aaro.

OGUN FUN IBA JEFUN JEDO.


A o po omi aloevera ati omi ayu pelu oyin po, o gbodo de ilaji kobu, a
o mu tan lekan soso.

OOGUN IBON TO DAJU


Mo Fi Olorun Oba Bewa Lati Sora Se Pelu Oogun Yii A O Gbodo Fi
Jale O.
A O Wa Eyin Ororo Kan, A O Fi Ito (urine) Alaboyun Se Ninu Ikoko
Aseje Tuntu. A o je tepotepo
Omo ti won ba fi oyun yen bi nikan lo le yin ibon funyan ti o maa
wole
Iba gbogbo ajunilo
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN SOMU RORO FUN OBINRIN


Ewe Ma Fowo Kan Omo Mi, Ireke, Ogede Wewe Kogbokogbo, Eru
Alamo, Epo Pupa Die, Ao Fi Omi Orounbo Se Ni Agbo Obinrin Yo
Ma Mu Yo Tun Mafi Fo Omu Re Pelu Ogo Oloun Eo Tun Gburo
Somu Roro Mo, Aye Wa Fun Ibere Lori Awon Oro Somun Roro Yi
Fun Enikeni Ao Ni Lugbade Aisan O.

RHEUMATISM FUN ARUNMOLEGUN*


Igo oyin kan aoda sori ina tiobatiun so kutuputu aoda Iru Woro si,
aoropo dada aowa sese sokale aoda Sinu Igo nla kan tiobati tutu
tan, odi Mimu nisibi kan laro ati lale.

OGUN IWOSAN LAGUNLAGUN


ao toju epo igi padoro,odidi atare mejo,orogbo mejo,ako
kanhun,ata ijosin,iyere,iyo isebe,ao gun ni agunmu,eko gbigbona
niki eniti lagunlagun tabi kokoro inu eje baja,mafi lo kotun gbodo
se mo,pelu ase olorun,iba eyin agba o

OGUN IWOSAN LAGUNLAGUN


AO toju epo-igi pandoro,odidi atare mejo,orogbo mejo,ako
kanhun,ata ijosi,iyere,iyo isebe,ao gun ni agunmu,eko gbigbona
niyo ma fi lo diedie,pelu ase olorun E Koni gburo aisan na mo

CURE WITH BITTER MELON (EGUSI BARA)


It treats blocked fallopian tube; Fibroids; Infections; Ovarian cyst
cancer; Arthritis and Low sperm count.
Recipe:-
Bitter melon (egusi bara)
Pap water (omidun)
Method:- Cut ur melon into pieces, pour pap water n cook at least,
30mins.
Take half glass first thing in d morning n last thing at night.
"Depending on ur body type", u can take a full glass also

NB: It might turn your tommy and make you parade convenient
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

room. But never mind, you are perfectly okay.

Bitter melon is also known as Egusi bara...Go to alagbo or elewe


omo or lekuleja any how you know them. Tell them you want bàrà.
Buy matured bàrà it works better.

CLEAN YOUR KIDNEYS


Here is an easy, cheap and simple way to do it. Take a bunch of fresh
green corriander leaves ( EFO EBOLO) and wash it clean. Cut it in
small pieces and put it in a pot. Pour clean water and boil it for ten
minutes and let it cool down.
Next filter it and pour it in a clean bottle and keep it in the
refrigerator to cool.

Drink one glass everyday and you will notice all salt and other
accumulated impurities coming out of your kidneys during
urination. You will be able to notice the difference yourself!

OPA EYIN RIRO.


Ao se epo igi ose(Baobab), to ba jina, ao file di ojo keji ki a to ma mu.

ARA RIRO.
Ao lo egusi inu eso botuje sinu ori fi ma wo ara.

OGUN IKO OMODE TODAJU


Ao fun omi orombo idaji coke, ao fi epo pupa idaji ilarin sii, ao fi
sugar die sii. Ao jii papo daadaa. Sibi imuko meji laro losan ati lale.
Hnmmm Osise pupo.

OGUN OKO OMODE


Epo pupa
Sugar onikoro bi woromeji
Atale die ( aogun ni o)ayuu (aogun papo, aoda epo lelori , tea spoon
fun omode laro losan ati ale
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

WOMAN HEALTH /REMEDY


Bring back your stop mensural Flow and Clear that vaginal and
womb infection..
For trying to conceive ladies once Ovulation started stop taking this
drink immediately
HEALTHY LIVING

If your period does not flow well(scanty)


Or you did abortion and since then you have issues of
infections,scanty flow or your period stopped when you have not
gotten to menopause age
Or you have any infection of the vaginal,womb
Don't worry
Get these and take it
Thank me later

INGREDIENTS

Ginger
Garlic
Tumeric
Cloves- this is zobo pepper for making zobo drink
NOTE you can get all from those selling zobo drink spices.

DIRECTION

Peel off dried skin,cut all and put in a clean container


Add clean water and keep for 2-3days.
After that take a glass of it in the morning 30min before eating and
before sleeping at night.
All traces of infection will disappear totally
You can repeat by adding water again and leave for 2days continue
the precedure
(females only)
Remember health is wealth
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO ARAN ( DEWORMING)


Eepo igi orogbo ati ewe Agunmona ao fi omi obi ( omi ikan) se, ao
ma mu.
Ti o ba di ijo keji ti a ba ya igbe eje kia wo igbe yen daada, ao ri awon
aran keke bi owu iranso funfun.

AKOKORO YORO
Ao lo alomu yio kunna ao wa fi sinu cup kan ao fi omi gbigbona die
si ao wa da si enu ni I Ibi ti akokoro nawa ao pa enu na de fun igba
die ao tu omi na danu ao tun se lekan tabi le meji ao se fun ojo meta
akokoro na yio silo (b)E da iyo sinu epo petrol ki E si fi owu gbe lori
eyin na leemarun lojo kan

OOGUN INU RIRUN


Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao
wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia
ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo
lo patapata lase edumare. O daju.

IDAKOLE(Amokole)
Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e,
ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.

OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE


Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni
gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro
eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo
n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna
daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti
o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo
omi lasan.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OORU INU (INTERNAL HEAT)


Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan
leemeji lojumo.

OGUN GIRI.
Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba
juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti
oyinbo
ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo
na.

OOGUN IKO TO DAJU


Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan,
alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole
ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi,
ajebiidan ni. Ao nii saisan o!

EGBOGI GBOGBONISE
isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo
gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan.
Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa
die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi
agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo
arun.

EGBOGI JEDIJEDI (OGUN JEDIJEDI)


egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu.

OGUN STROKE
Omin igbin topo Dada ewe taba tutu ao gbo iwon OMI taba ri ninu
ewe yi ni iwon OMI igbin yi gbodo je pelu iwon oyun igan ao da
papo sinu igo tabi ike kan leyin ojo KEJI idi mimun haaaa ise ni sa
odaju bi iku iba eyin agba o
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OOGUN INU RIRUN


Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao
wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia
ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo
lo patapata lase edumare. O daju.

IDAKOLE AMOKOLE
Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e,
ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.

OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE


Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni
gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro
eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo
n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna
daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti
o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo
omi lasan.

OORU INU(INTERNAL HEAT)


Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan
leemeji lojumo.

OGUN GIRI.
Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba
juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti
oyinbo
ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo
na.

OOGUN IKO TO DAJU


Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan,
alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi,
ajebiidan ni. Ao nii saisan o!

ATOSI
odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu
da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta.
Odaju

AKOKORO
Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu
egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju
o.

EGBOGI GBOGBONISE
isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo
gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan.
Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa
die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi
agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo
arun.

EGBOGI JEDIJEDI (OGUN JEDIJEDI)


egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu.

OGUN STROKE
Omin igbin topo Dada ewe taba tutu ao gbo iwon OMI taba ri ninu
ewe yi ni iwon OMI igbin yi gbodo je pelu iwon oyun igan ao da
papo sinu igo tabi ike kan leyin ojo KEJI idi mimun haaaa ise ni sa
odaju bi iku iba eyin agba o

OGUN IKO/COUGH
Oyin Gidi, osan wewe, ati adin. Gbogbo idaji igo kid. Aodapo. Fun
omode sibi kan laro ati lale. Omona yio mabi tabi ya igbe.
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN LAPALAPA
Ila Tutu Kan, Osun Die, Kanhun Bilala Die, Agun Pomo Ose Dd ,
Lilore: Leyin Igbati Abafi Apadi Haa Ibe Tan Afi Ose Naa Kan Omi
Fira Ibe

OGUN KOKORO ARA:*


ewe taba tutu, aidan, enu opiri, eru alamo, ao gun po, ao da die sinu
ipara wa, ao po iyoku mo ose dudu tabi eyikeyi, ao ma fi we.. Odara
lopolopo

FUN KOKORO ARA EYIKEYI


Ifo,eela, tabi lapa
Elo wa imi-ojo, e lo kuna bi elubo. E da kerosene die mo ki o mu
Dada, e lo atare meta mo. Ki e ma fi pa ibe.
Olorunlogbontan

OGU LAPALAPA
imiojo pelu eyin aro amri eyin aro yi Ni odo awon olose dudu amalo
imiojo yi si inu eyin aro ama bo oju lapalapa yi aoma fi ra oju re ti
aba ti we ton

OGUN FUN OMODE TI ORUN RE KODURO TABI EGUN RE


KOLE DADA
Ao fi egun esin tele oru ao wa omo onigedegede ewe kasu ewe iranje
ao dalelori bimose toyen aose lagbo kiama fiwe ao tun mafun omo
naa mu diedie

OGUN FUN OBINRIN TIKORI OYUN NI


Ewe patanmo emoagbo emo ajao eku emo kan pelu odidi atare kan
ao jopo obinrin naa ni yio mafi ebu yi foko tutu mu ni ojo keji toba
pari nkan alejo re kosi gbudo sunmo oko re fun ojo marun pelu ogo
olorun yio ni oyun

OGUN ARAN YOYUNYOYUN


Isuogede Wewe Egbo Isepe Agbe Egbo Idagba Aolopo Aofi Eje Esu
Se Fun Obinrin Naje Nigbati Osu Bati Yaduro Lara Re Aran Kotun
Niyo Oyun Re Mo
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AWOGBA ARUN FUN ENITO NWA OYUN


Eepo Oganwo Egbo Ogede Wewe Egbo Seregun Egboipeta Ako
Kanwun Egbo Ewon Agogo Aose Jina Obinrin Na Mimu Ati Wiwe
Nifun Obinrin Na

OKO_TI_KOKIN_LETAN_TOBAFE_SE_JIMOHU
Poporo oka baba,
Bara 1,
Epa ikun
Aoge gbogbore si wewe, aokosi inu Igo, aobu HOT Lee Lori, aoma
mu die die,
Hmmmm, oko na yiole ti gbogbo isan arare yio jade tan daradara,
kosi tunni tete da enu kole.

OGUN_EJE_RURU_HYPERTENSION
Ata ilé funfun
Alubosa ayuu
Alubosa elewe
Alubosa funfun
Aloe Vera
Madunmaro tutu
Aogun wan papo dada, aokowan sì inú ike ñlá kan, aobu omi die si,
tí obadi ni ojo keji, aowa fi à?? ?e dada (filter) aoro sinu ike
olomori, aobu ojúlówó oyin igan sì l?p?l?p?, aomamu diedie,
osise pup?.

OGBE NU (HULCER)
ogede agbagba dudu ao ge bi Eni pe afefi din dodo ao wa sa si Abe
ile tabi inu yara tobagbe dada aolo kunna dada ao mafi wara tabi
milk lo siwaju ki ato jeun aro
EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN HYPERTENSION,
Eso pandoro ao sa ti yio gbe dada ao wa lo kunna dada ao mafi mu
eko gbigbona sun lalale

OGUN EJE RURU HYPERTENSION /H.B.P


Ao Ja Eso Isin Toba Pon Daadaa,ao Jo Pelu Odindi Atare Kan,ao
Maa Fi Coca Cola Loo Daaadaa.

HYPERTENSION
Ishapa mala ( Hausa), at are topo die,kanafuru die,sugar onikoro
bi meji si meta, asegbogbo repapo, aomamu ni tombila kan laro ati
lale

HYPERTENSION
o aolo wa obi abata META, atale merin, ayu die, ao ge gbogbo resi
wewe, aoda sinu omin osan wewe abi inu oti oyinbo fun ojo meji
aowa mamu ni sibi meji meji lemeji lojumon CONFIRM

HYPERTENSION
Ogun ki Aya didun ma dun yon, ao wa eso pear nla meje ao sa sinu
orun yio gbe dada ao lo yio kunna ao to jure fun lilo ao bu sibi ijeun
meji sinu eko gbigbona laro laro ose kan warri iya to titi osu kan
gbogbo retilo

ITO SUGA
Ao wa ewe ewuro ati ewe efirin ao gbo papo pelu omi die ao se omi
na ao lo alubosa ayu sinu re ao gbe kana ao mamu ni aro ati ale ao ri
pe a mu gbogbo eyi ni ase tan ni ojo kan ni ojo keji ao se omiran bee
ni ao ma se ni ojojumo fun osu kan ito sugar yio si lo

EYIN RIRO BACK PAIN


ewe atoo ati ori, ao gun po, ao ma fi wo eyin na ?

S-ar putea să vă placă și